Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
DECEMBER 2017
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JANUARY 29–FEBRUARY 25, 2018
© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
CÔTE D’IVOIRE
Orílẹ̀-èdè Côte d’Ivoire rèé, Ivory Coast ni wọ́n ń pè é tẹ́lẹ̀. Ibẹ̀ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ibi tí wọ́n ti ń gbin kòkó jù lọ lágbàáyé, kòkó yìí sì ni wọ́n fi ń ṣe ṣokoléètì. Inú oòrùn ni wọ́n máa ń sá a sí kó lè gbẹ. Aṣáájú-ọ̀nà kan ń fi àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì tó wà nínú ìwé Ìròyìn Ayọ̀ han ẹnì kan tó ń sá kòkó
IYE AKÉDE
11,133
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
28,274
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2016)
76,526
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.