Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí
Ọ̀SẸ̀ APRIL 2-8, 2018
3 Jẹ́ Onígbọràn Kó O sì Nígbàgbọ́ Bíi Ti Nóà, Dáníẹ́lì àti Jóòbù
Ọ̀SẸ̀ APRIL 9-15, 2018
8 Ṣé O Mọ Jèhófà Dáadáa Bíi Ti Nóà, Dáníẹ́lì àti Jóòbù?
Èèyàn bíi tiwa ni Nóà, Dáníẹ́lì àti Jóòbù, irú àwọn ìṣòro tá à ń kojú lónìí làwọn náà sì kojú. Àmọ́, kí ló mú kí wọ́n jẹ́ olóòótọ́ àti onígbọràn? Báwo ni wọ́n ṣe dẹni tó mọ Jèhófà dáadáa débi pé kò sóhun tó ba àjọṣe wọn pẹ̀lú rẹ̀ jẹ́? A máa rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè yìí nínú àwọn àpikẹ̀kọ yìí.
13 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Ohun Gbogbo Ṣeé Ṣe Lọ́dọ̀ Jèhófà
Ọ̀SẸ̀ APRIL 16-22, 2018
18 Kí Ló Túmọ̀ Sí Pé Kéèyàn Jẹ́ Ẹni Tẹ̀mí?
Ọ̀SẸ̀ APRIL 23-29, 2018
23 Sapá Láti Túbọ̀ Di Ẹni Tẹ̀mí
Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ máa jẹ́ ká mọ ohun tó túmọ̀ sí pé kéèyàn jẹ́ ẹni tẹ̀mí àti ẹ̀kọ́ tá a lè rí kọ́ lára àwọn tó jẹ́ ẹni tẹ̀mí. Nínú àpilẹ̀kọ kejì, a máa jíròrò bá a ṣe lè túbọ̀ di ẹni tẹ̀mí àti bá a ṣe lè fi hàn pé a jẹ́ ẹni tẹ̀mí nínú àwọn ìpinnu tá à ń ṣe lójoojúmọ́.