Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
FEBRUARY 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: APRIL 2-29, 2018
© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ
KÀǸBÓDÍÀ
Tọkọtaya kan ń wàásù fún ìyá kan tó lọ gbé ọmọ rẹ̀ nílé ìwé. Ó wé síkáàfù bí wọ́n ṣe máa ń wé e ní ìlú wọn
IYE AKÉDE
1,021
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
2,524
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2016)
2,790
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.