Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
MARCH 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: APRIL 30–JUNE 3, 2018
© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
CROATIA
Àwọn arákùnrin méjì ń wàásù fún kunlékunlé kan tó jókòó sórí afárá tó wà níwájú ilé tí wọ́n ń pè ní Kaštilac, nítòsí ìlú Split, ilé ọ̀hún ti wà láti ọgọ́rùn-ún ọdún kẹrìndínlógún
IYE AKÉDE
5,335
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
2,123
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2016)
8,434
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.