Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JUNE 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: AUGUST 6–SEPTEMBER 2, 2018
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
URUGUAY
Àwọn arábìnrin méjì ń wàásù fún ọkùnrin kan nínú ṣọ́ọ̀bù rẹ̀ nílùú Montevideo, olú ìlú Uruguay
IYE AKÉDE
11,711
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
9,001
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2017)
23,426
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.