Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JULY 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: SEPTEMBER 3-30, 2018
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ:
BỌ̀GÉRÍÀ
Bí wọ́n ṣe máa ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú àwọn tó nífẹ̀ẹ́ sí òtítọ́ rèé nínú ẹ̀wọ̀n lórílẹ̀-èdè Bọ̀géríà
IYE AKÉDE
2,475
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
2,950
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2017)
5,327
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò