Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí
Ọ̀SẸ̀ OCTOBER 1-7, 2018
Ọ̀SẸ̀ OCTOBER 8-14, 2018
8 Má Ṣe Máa Fi Ìrísí Dáni Lẹ́jọ́
Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ sọ̀rọ̀ nípa àwọn nǹkan tó lè mú kó ṣòro fún wa láti rí àrídájú ọ̀rọ̀. Ó wá sọ àwọn ìlànà Bíbélì táá jẹ́ ká lè máa gbé ọ̀rọ̀ yẹ̀ wò dáadáa ká lè ṣe ìpinnu tó tọ́. Àpilẹ̀kọ kejì sọ ohun mẹ́ta táwọn èèyàn sábà máa ń wò tí wọ́n bá ń pinnu irú ẹni táwọn míì jẹ́. Ó tún jíròrò ohun tá a lè ṣe tá ò fi ní máa ṣe ojúsàájú.
13 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Mo Pinnu Pé Mi Ò Ní Juwọ́ Sílẹ̀
Ọ̀SẸ̀ OCTOBER 15-21, 2018
18 A Máa Láyọ̀ Tá A Bá Jẹ́ Ọ̀làwọ́
Ọ̀SẸ̀ OCTOBER 22-28, 2018
23 Máa Bá Jèhófà Ṣiṣẹ́ Lójoojúmọ́
Jèhófà dá àwa èèyàn ká lè gbádùn ìgbésí ayé wa, ká sì láyọ̀. Tá a bá ń lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ Jèhófà lójoojúmọ́, tá a sì ń rí bí ohun tá à ń ṣe ṣe ń mú kí ìfẹ́ Ọlọ́run ṣẹ, ó dájú pé a máa láyọ̀. Àwọn àpilẹ̀kọ yìí sọ onírúurú ọ̀nà tá a lè gbà jẹ́ ọ̀làwọ́ àtàwọn àǹfààní tá a máa rí.