Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
AUGUST 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: OCTOBER 1-28, 2018
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
MÀLÁWÌ
Alábòójútó àyíká kan àti ìyàwó rẹ̀ fẹ́ rìnrìn-àjò lọ sí ìjọ míì tí wọ́n fẹ́ bẹ̀ wò. Wọ́n kó àwọn ìwé, ẹ̀rọ tó ń gbé àwòrán jáde, ẹ̀rọ gbohùn-gbohùn àti èyí tó pọ̀ jù nínú ẹrù wọn sorí kẹ̀kẹ́
IYE AKÉDE
93,412
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
145,504
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2017)
315,784
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.