Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
OCTOBER 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: DECEMBER 3-30, 2018
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
FẸNẸSÚÉLÀ
Ìyá kan àtàwọn ọmọ rẹ̀ ń gbádùn ìpápánu nígbà tí wọ́n wà lóde ẹ̀rí ní Telares de Palo Grande, Caracas
IYE AKÉDE
149,355
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
209,866
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2017)
478,266
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.