Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí
3 1918—Ní Ọgọ́rùn-Ún Ọdún Sẹ́yìn
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 3-9, 2018
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 10-16, 2018
Irọ́ pípa ti gbalẹ̀ gbòde lónìí. Ta ló pa irọ́ àkọ́kọ́? Irọ́ wo ló burú jù tẹ́nì kan ti pa? Báwo la ṣe lè dáàbò bo ara wa káwọn míì má bàa fi irọ́ tàn wá jẹ, báwo la sì ṣe lè máa bá ara wa sọ òtítọ́? Báwo la ṣe lè lo Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ lóde ẹ̀rí? Àwọn àpilẹ̀kọ yìí máa ṣàlàyé.
17 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Jèhófà Bù Kún Ìpinnu Tí Mo Ṣe
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 17-23, 2018
22 Fọkàn Tán Kristi Tó Jẹ́ Aṣáájú Wa
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 24-30, 2018
27 Bó O Ṣe Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn Láìka Ìyípadà Èyíkéyìí Sí
Torí a jẹ́ aláìpé, tí nǹkan bá yí pa dà nígbèésí ayé wa tàbí nínú ètò Ọlọ́run, kì í bára dé lọ́pọ̀ ìgbà. Àwọn àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí máa jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè ní ìbàlẹ̀ ọkàn ká sì fọkàn tán Kristi tó jẹ́ Aṣáájú wa nígbà tí nǹkan bá yí pa dà láìròtẹ́lẹ̀.
32 Ǹjẹ́ O Mọ̀?