Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
NOVEMBER 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: DECEMBER 31, 2018–FEBRUARY 3, 2019
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
SWEDEN
Àwọn akéde nílùú Stockholm lo àǹfààní bójú ọjọ́ ṣe mọ́lẹ̀ rekete lọ́wọ́ ìrọ̀lẹ́ láti wàásù. Wọ́n máa ń wàásù fáwọn onítakisí, àwọn tó ń tajà, àwọn tó ń ta epo àtàwọn míì tó ń ṣiṣẹ́ lálẹ́
IYE AKÉDE
22,418
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
10,027
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2017)
34,966
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.