Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ ÌRÒYÌN YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 14: June 3-9, 2019
2 Ǹjẹ́ Ò Ń Ṣe Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Láṣeyanjú?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 15: June 10-16, 2019
8 Fara Wé Jésù Kó O Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 16: June 17-23, 2019
14 Rọ̀ Mọ́ Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ipò Táwọn Òkú Wà
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 17: June 24-30, 2019
20 Jẹ́ Kí Jèhófà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Borí Àwọn Ẹ̀mí Èṣù
26 Ìtàn Ìgbésí Ayé—A Rí “Péálì Kan Tó Níye Lórí Gan-An”
31 Ǹjẹ́ O Mọ̀?—Báwo làwọn èèyàn nígbà àtijọ́ ṣe máa ń ṣètò láti bá ọkọ̀ ojú omi rìn?