Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
APRIL 2019
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JUNE 3-30, 2019
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Lẹ́yìn tí Jésù jíǹde, ó bá àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sọ̀rọ̀, ó sì pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n ‘lọ, kí wọ́n sì máa sọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn’ (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 14, ìpínrọ̀ 1)