Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Ẹ̀bùn Tó Dáa Jù Tí Mo Gbà Láyé Mi
Kí ló sún ẹni tó jẹ́ ọ̀gá nídìí tẹníìsì gbígbá láti di ẹni tó ń fi ọ̀pọ̀ wákàtí wàásù nípa Bíbélì?
(Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀLÀÁFÍÀ ÀTI AYỌ̀.)
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bí Ẹ Ṣe Lè Máa Fìfẹ́ Hàn Síra Yín
Báwo ni tọkọtaya ṣe lè fi hàn pé àwọn nífẹ̀ẹ́ ara àwọn dénú? Wo àbá mẹ́rin tó dá lórí àwọn ìlànà tó wà nínú Bíbélì.
(Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ.)