Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JUNE 2019
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: AUGUST 5–SEPTEMBER 1, 2019
© 2019 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Jèhófà fàánú hàn sí Lọ́ọ̀tì nígbà tó rán àwọn áńgẹ́lì láti gba òun àti ìdílé rẹ̀ là (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 26, ìpínrọ̀ 4)