Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ ÌRÒYÌN YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 27: September 2-8, 2019
2 Ìsinsìnyí Gan-An Ni Kó O Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Múra Sílẹ̀ fún Inúnibíni
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 28: September 9-15, 2019
8 Máa Sin Jèhófà Nìṣó Tí Wọ́n Bá Tiẹ̀ Fòfin De Iṣẹ́ Wa
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 29: September 16-22, 2019
14 ‘Ẹ Lọ, Ẹ Máa Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn’
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 30: September 23-29, 2019
20 Bá A Ṣe Lè Wàásù fún Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Kankan