Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JULY 2019
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ:SEPTEMBER 2-29, 2019
© 2019 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Àwọn akéde Ìjọba Ọlọ́run máa ń fìfẹ́ hàn sáwọn tó wá láti ilẹ̀ tí wọn ò ti gba ẹ̀sìn Kristẹni, wọ́n sì máa ń jẹ́ kí wọ́n mọ bí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe ń ṣeni láǹfààní (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 30, ìpínrọ̀ 12 àti 13)