Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì Jw.Org
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bó O Ṣe Lè Bá Ọmọ Ẹ Sọ̀rọ̀ Nípa Ọtí
Ìgbà wo ló yẹ káwọn òbí bá àwọn ọmọ wọn sọ̀rọ̀ nípa ọtí, báwo ló sì ṣe yẹ kí wọ́n bá wọn sọ ọ́?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ > ỌMỌ TÍTỌ́.
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Bí Àwọ̀ Ẹja Àbùùbùtán Ṣe Máa Ń Fọ Ara Ẹ̀
Kí ló mú káwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì máa wá bí wọ́n á ti ṣe ohun kan sára ọkọ̀ ojú omi táá jọ ohun tó wà lára ẹja àbùùbùtán?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌMỌ̀ SÁYẸ́ǸSÌ ÀTI BÍBÉLÌ > TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?