Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
SEPTEMBER 2019
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: OCTOBER 28–DECEMBER 1, 2019
© 2019 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Àpọ́sítélì Jòhánù rí “ogunlọ́gọ̀ èèyàn” tí wọ́n wọ aṣọ funfun, imọ̀ ọ̀pẹ sì wà lọ́wọ́ wọn (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 39, ìpínrọ̀ 2)