Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì Jw.Org
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Báwo ni àwọn méjì tí wọn ò wá láti ilé kan náà, tí ọjọ́ orí wọn sì yàtọ̀ síra ṣe di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ bẹ́ẹ̀? Báwo ni àpẹẹrẹ wọn ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti ní ọ̀rẹ́ gidi?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÀGBỌ́ NÍNÚ ỌLỌ́RUN > TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN.
On jw.org, go to BIBLE TEACHINGS > FAITH IN GOD > IMITATE THEIR FAITH.
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Bí Èèrà Talamọ́ Ṣe Ń Nu Ìdọ̀tí Ara Rẹ̀
Kòkòrò kékeré yìí gbọ́dọ̀ máa nu ìdọ̀tí tó bá yí i lára kó má bàa kú. Báwo ló ṣe máa ń ṣe iṣẹ́ pàtàkì yìí?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌMỌ̀ SÁYẸ́ǸSÌ ÀTI BÍBÉLÌ > TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?