Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì Jw.Org
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Kí Ló Dé Tó Jẹ́ Ọ̀rọ̀ Tí Ò Dáa Ló Máa Ń Jáde Lẹ́nu Mi Ṣáá?
Kí ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí wàá fi máa ronú kó o tó sọ̀rọ̀?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > Ọ̀DỌ́ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Wọ́n Bá Ń Halẹ̀ Mọ́ Ọmọ Mi?
Wo ohun mẹ́rin tó o lè ṣe kí ọmọ ẹ lè kápá ẹni tó ń halẹ̀ mọ́ ọn.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ > ỌMỌ TÍTỌ́.