Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
NOVEMBER 2019
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: DECEMBER 30, 2019–FEBRUARY 2, 2020
© 2019 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Àlùfáà àgbà wọnú Ibi Mímọ́ Jù Lọ ní Ọjọ́ Ètùtù, ó fi ọwọ́ kan gbé tùràrí dání, ó sì fi ọwọ́ kejì gbé ìkóná tó kún fún ẹyin iná. Lẹ́yìn tó da tùràrí sínú ẹyin iná, gbogbo iyàrá náà kún fún òórùn dídùn. Ẹ̀yìn ìyẹn ló tún pa dà wá sínú Ibi Mímọ́ Jù Lọ láti fi ẹ̀jẹ̀ rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 47, ìpínrọ̀ 4)