Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Ọ̀pọ̀ ló fẹ́ mọ̀ nípa wíwo ìràwọ̀, bíbá ẹ̀mí lò, àwọn àǹjọ̀nú, iṣẹ́ oṣó àti àjẹ́. Àmọ́ àwọn ewu kan wà tó yẹ kó o mọ̀. Kí làwọn ewu náà?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > Ọ̀DỌ́ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.
ǸJẸ́ O MỌ̀?
Ìwádìí Àwọn Awalẹ̀pìtàn Jẹ́ Ká Rí I Pé Ọba Dáfídì Gbé Láyé Rí Lóòótọ́
Àwọn alárìíwísí kan sọ pé ìtàn àròsọ lásán ni ìtàn Ọba Dáfídì, pé àwọn èèyàn ló hùmọ̀ ẹ̀. Àmọ́ kí làwọn awalẹ̀pìtàn rí?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌTÀN ÀTI BÍBÉLÌ > ÒÓTỌ́ NI ÀWỌN ÌTÀN INÚ BÍBÉLÌ.