Ìròyìn Iṣẹ́-ìsìn April
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 371 136.7 10.3 57.4 9.7
Aṣá. Dééd. 17,016 71.8 6.1 26.7 6.0
Aṣá. Olù. 10,197 56.0 4.4 16.9 3.4
Akéde 162,775 10.8 0.8 3.4 0.9
ÀRÒPỌ̀ 190,359 Àwọn Tí A Batisí: 333
Inú wá dùn gidigidi láti tún ròyìn góńgó titun kẹrin tí ó tẹ̀léra nínú akéde. A ní 190,359 ní April. A tún ní góńgó mìíràn nínú aṣáájú-ọ̀nà déédéé—17,016. Àwọn ìjọ 3,531 ni ó ti forúkọ sílẹ̀ nísinsìnyí, ní báyìí nínú ọdún iṣẹ́-ìsìn lọ́ọ́lọ́ọ́ a ti ní 9,533 tí ó ṣe batisí.