ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 3/96 ojú ìwé 7
  • Àwọn Ìfilọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ìfilọ̀
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1996
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1996
km 3/96 ojú ìwé 7

Àwọn Ìfilọ̀

◼ Àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a óò fi lọni ní March: Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun fún ₦80. April àti May: Àsansílẹ̀-owó fún Ilé-Ìṣọ́nà. Fún ìpínlẹ̀ tí a ń ṣe lemọ́lemọ́, a tún lè lo ìwé pẹlẹbẹ èyíkéyìí (yàtọ̀ sí ìwé pẹlẹbẹ Education àti School). Níbi tí a bá ti fi ìfẹ́ hàn nígbà ìpadàbẹ̀wò, a lè fi àsansílẹ̀-owó lọni. June: Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun. Bí ìyẹn kò bá sí lárọ̀ọ́wọ́tó, lo ìwé Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí, Mankind’s Search for God, tàbí ìwé olójú ewé 192 èyíkéyìí. ÀKÍYÈSÍ: Àwọn ìjọ tí yóò nílò àwọn ìwé ìgbétásì tí a mẹ́nu kàn lókè yìí ní láti béèrè fún wọn lórí Literature Order Form (S-14) olóṣooṣù wọn, ti oṣù tí ń bọ̀.

◼ Kí alábòójútó olùṣalága tàbí ẹnì kan tí òún yàn ṣàkọsílẹ̀ àkáǹtì ìjọ ní March 1 tàbí bí ó bá ti lè ṣeé ṣe kí ó yá tó lẹ́yìn náà. Ẹ ṣe ìfilọ̀ fún ìjọ lẹ́yìn tí ẹ bá ti ṣe èyí.

◼ Gẹ́gẹ́ bí a ti ṣèfilọ̀ nínú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti January 1996, a óò sọ ọ̀rọ̀ àsọyé ìtagbangba àkànṣe fún àkókò Ìṣe Ìrántí ní ọdún yìí ní Sunday, April 21, ní ọ̀pọ̀ jù lọ ìjọ. Ẹṣin ọ̀rọ̀ àsọyé náà yóò jẹ́, “Wíwà Láìlẹ́bi Láàárín Ìran Oníwà Wíwọ́ Kan.” Ẹ ṣe àkànṣe ìsapá láti pe àwọn tí ó wá sí ibi Ìṣe Ìrántí ní April 2 wá síbẹ̀.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́