Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn January
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 422 131.9 11.8 59.6 10.5
Aṣá. Dééd. 17,853 71.8 6.6 27.0 5.7
Aṣá. Olù. 6,180 57.8 4.3 17.1 3.5
Akéde 169,508 11.4 0.9 3.8 1.0
ÀRÒPỌ̀ 193,963 Àwọn Tí A Batisí: 1,048
A láyọ̀ láti ròyìn góńgó tuntun tí a tí ì ní rí nínú akéde, tí ó jẹ́ 193,963 tí ó ròyìn fún January. Èyí fi 2,363 ju góńgó wa tí ó kẹ́yìn ní November. Àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé lọ sókè sí 17,853. A ní 3,659 ìjọ ní Nàìjíríà nísinsìnyí.