Ìròyìn Ìṣàkóso Ọlọ́run
Benin: Orílẹ̀-èdè kékeré yìí dé góńgó akéde rẹ̀ karùndínláàádọ́ta tẹ̀lératẹ̀léra ní September, pẹ̀lú 4,843 tí ó ròyìn.
Bolivia: Góńgó tuntun 3,944 akéde ròyìn ní September. Èyí jẹ́ ìlọsókè ìpín 6 nínú ọgọ́rùn-ún ju ti ọdún tí ó kọjá. Àwọn akéde ìjọ ní ìpíndọ́gba 13.4 wákàtí nínú iṣẹ́ ìsìn pápá.