Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn July
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 449 136.9 11.0 62.7 11.0
Aṣá. Déédé 19,234 67.9 6.0 25.0 5.6
Aṣá. Olù. 4,606 56.3 4.2 16.6 3.8
Akéde 176,584 10.6 0.8 3.6 1.0
ÀRÒPỌ̀ 200,873 Àwọn Tí A Batisí: 654
Àwọn 200,873 tí wọ́n ròyìn ní July jẹ́ góńgó tí ó tí ì ju ti ìgbàkígbà rí lọ. Èyí fi 387 akéde ju góńgó tí a ní kẹ́yìn ní August 1996. Nísinsìnyí, a ní ìjọ 3,918 tí a forúkọ wọn sílẹ̀.