Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn September
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 461 136.8 10.7 61.8 10.9
Aṣá. Déédé 19,626 66.4 5.9 24.7 5.5
Aṣá. Olù. 6,478 57.3 3.8 16.7 3.6
Akéde 178,495 10.7 0.8 3.6 1.0
ÀRÒPỌ̀ 205,060 Àwọn Tí A Batisí: 824
Inú wá dùn pé a bẹ̀rẹ̀ ọdún iṣẹ́ ìsìn wa tuntun pẹ̀lú góńgó tí ó tí ì ju ti ìgbàkígbà rí lọ ti 205,060 akéde. Èyí ni ìtòtẹ̀léra góńgó kẹta láti July 1997. Àwọn 19,626, aṣáájú ọ̀nà déédéé tí wọ́n ròyìn tún jẹ́ góńgó tuntun kan. Nísinsìnyí, a ní ìjọ 3,953 tí a forúkọ wọn sílẹ̀.