Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn October
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 520 136.2 11.9 64.6 11.3
Aṣá. Déédé 19,639 66.5 6.0 24.2 5.5
Aṣá. Olù. 5,408 56.7 3.9 16.5 3.7
Akéde 180,247 10.8 0.8 3.5 1.0
ÀRÒPỌ̀ 205,814 Àwọn Tí A Batisí: 938
Inú wa dùn láti ròyìn góńgó tuntun ju ti ìgbàkígbà rí lọ ti 205,814 akéde. Èyí mú kí ó jẹ́ góńgó tuntun wa ju ti ìgbàkígbà rí lọ ẹlẹ́ẹ̀kejì láti ìgbà tí ọdún iṣẹ́ ìsìn tuntun yìí ti bẹ̀rẹ̀. Ó tún jẹ́ góńgó tuntun wa léraléra ìgbà kẹrin láti July 1997. Àwọn 19,639 aṣáájú ọ̀nà déédéé tí ó ròyìn tún jẹ́ góńgó tuntun pẹ̀lú. A ní ìjọ 3,968 tí wọ́n forúkọ sílẹ̀ nísinsìnyí.