ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 5/98 ojú ìwé 7
  • Àwọn Ìfilọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ìfilọ̀
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1998
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1998
km 5/98 ojú ìwé 7

Àwọn Ìfilọ̀

◼ Àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a óò fi lọni ní May: Gbogbo èdè—Àsansílẹ̀ owó fún Ilé Ìṣọ́ àti Jí! Àwọn ìwé ìròyìn ẹlẹ́ẹ̀mejì lóṣù fún ọdún kan: ₦280. Ẹlẹ́ẹ̀kan lóṣù fún ọdún kan tàbí ẹlẹ́ẹ̀mejì lóṣù fún oṣù mẹ́fà: ₦140. June - September: A lè fi èyíkéyìí nínú àwọn ìwé olójú ewé 192 yàtọ̀ sí ìwé Àṣírí Ayọ̀ Ìdílé, Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun, Iwe-Amọna Ile Ẹkọ Iṣẹ Ojiṣẹ Ijọba Ọlọrun, àti Iṣetojọ Lati Ṣaṣepari Iṣẹ-ojiṣẹ Wa lọni ní ẹ̀dínwó ₦20. A fi lẹ́tà kọ̀ọ̀kan ránṣẹ́ sí gbogbo ìjọ àti ẹgbẹ́ àwọn alàgbà nípa èyí ní oṣù March. ÀKÍYÈSÍ: Kí àwọn ìjọ tí yóò bá nílò àwọn ìwé ìgbétáásì tí a mẹ́nu kàn lókè yìí béèrè fún wọn lórí Literature Order Form (S-14) olóṣooṣù wọn ti oṣù tí ń bọ̀.

◼ Nínú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti April 1998, a kéde pé ìwé àṣàrò kúkúrú náà, Ireti Wo ni Ó Wà fun Awọn Ololufẹ Tí wọn Ti Kú? ti wà lọ́wọ́ báyìí ní èdè Edo, Itsekiri, àti Ogoni. Ẹ jọ̀wọ́, ẹ kíyè sí i pé ìwé àṣàrò kúkúrú yẹn kò sí lọ́wọ́ ní èdè Ogoni, ṣùgbọ́n ó wà ní èdè Khana.

◼ Bẹ̀rẹ̀ ní ọ̀sẹ̀ September 21, 1998, a óò máa ka ọ̀wọ́ àwọn ìwé pẹlẹbẹ ní Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ìwé Ìjọ, yóò bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìwé pẹlẹbẹ náà, Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?

◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tuntun Tí Ó Wà:

Lasting Peace and Happiness—How to Find Them —Gẹ̀ẹ́sì

Watch Tower Publications Index 1996 —Gẹ̀ẹ́sì

◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tí Ó Wà Nísinsìnyí:

Àṣírí Ayọ̀ Ìdílé —Gẹ̀ẹ́sì

Gbádùn Iwalaaye lori Ilẹ Ayé Titilae! —Gẹ̀ẹ́sì, Yoruba

Ìdìpọ̀ Ilé Ìṣọ́ ti 1982 —Gẹ̀ẹ́sì

Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun —Ẹ́fíìkì

Iwe Itan Bibeli Mi —Gẹ̀ẹ́sì

Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa? —Ìgbò

Kọrin Ìyìn sí Jehofah (Ńlá) —Gẹ̀ẹ́sì

Orukọ Atọrunwa naa Tí Yoo Wà Titilae —Gẹ̀ẹ́sì

Our Problems—Who Will Help Us Solve Them? —Gẹ̀ẹ́sì

Revelation—Its Grand Climax At Hand! —Ìgbò

The Path of Divine Truth Leading to Liberation —Gẹ̀ẹ́sì

There Is Much More to Life! —Gẹ̀ẹ́sì

Victory Over Death—Is It Possible for You? —Gẹ̀ẹ́sì

◼ Àwọn Compact Disc Tuntun Tí Ó Wà:

Kingdom Melodies Àkójọ 5

◼ Àwọn Kásẹ́ẹ̀tì Àtẹ́tísí Tuntun Tí Ó Wà:

Àṣírí Ayọ̀ Ìdílé —Gẹ̀ẹ́sì

Why Respect Theocratic Arrangements? (Àwòkẹ́kọ̀ọ́, kásẹ́ẹ̀tì ẹlẹ́yọkan) —Gẹ̀ẹ́sì

◼ Kásẹ́ẹ̀tì Fídíò Tuntun Tí Ó Wà:

Jehovah’s Witnesses—The Organization Behind the Name —Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà

◼ Àwọn Kásẹ́ẹ̀tì Àtẹ́tísí Tí Ó Wà Nísinsìnyí:

Doing What Is Right in Jehovah’s Eyes —Gẹ̀ẹ́sì

Iwe Itan Bibeli Mi (ẹyọ kásẹ́ẹ̀tì 4 nínú álúbọ́ọ̀mù) —Gẹ̀ẹ́sì

Jehovah Delivers Those Calling Upon His Name —Gẹ̀ẹ́sì

Jehovah’s Name to Be Declared in All the Earth —Gẹ̀ẹ́sì

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́