Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn February
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 466 134.1 13.4 60.8 10.8
Aṣá. Déédé 20,035 64.6 6.3 23.5 5.4
Aṣá. Olù. 5,690 55.0 3.8 15.6 3.5
Akéde 180,708 10.3 0.8 3.4 0.9
ÀRÒPỌ̀ 206,899 Àwọn Tí A Batisí: 187
Inú wa dùn láti tún ròyìn góńgó tuntun ju ti ìgbàkígbà rí lọ ti 206,899 akéde tí ó ròyìn ní oṣù February. Èyí ni góńgó wa kẹrin nínú ọdún iṣẹ́ ìsìn yìí. Bákan náà, fún ìgbà àkọ́kọ́, a ré kọjá ìlà 20,000 aṣáájú ọ̀nà déédéé, nítorí 20,035 ni ó ròyìn ní oṣù yìí. Iye àwọn tí a ti batisí báyìí nínú ọdún iṣẹ́ ìsìn yìí jẹ́ 13,638. Èyí fí ìpín 6 nínú ọgọ́rùn-ún ju iye tí a batisí ní àkókò kan náà lọ́dún tí ó kọjá.