Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn April
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 411 134.5 11.7 60.3 10.9
Aṣá. Déédé 20,744 66.1 6.5 23.5 5.3
Aṣá. Olù. 16,869 53.5 3.8 14.3 3.1
Akéde 169,169 10.4 0.8 3.30.9
ÀRÒPỌ̀ 207,193 Àwọn Tí A Batisí: 247
Inú wa dùn láti ròyìn góńgó tuntun ju ti ìgbàkígbà rí lọ ti 207,193 tí ó ròyìn ní oṣù April. Àwọn 20,744 aṣáájú ọ̀nà déédéé jẹ́ góńgó tuntun pẹ̀lú. Ní báyìí, a ní 4,013 ìjọ.