Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn June
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 443 130.4 11.7 58.2 10.1
Aṣá. Déédé 20,507 63.8 6.5 23.4 5.4
Aṣá. Olù. 6,535 54.0 4.3 15.8 3.5
Akéde 180,738 10.1 0.8 3.4 1.0
ÀRÒPỌ̀ 208,223 Àwọn Tí A Batisí: 817
Inú wa dùn láti ròyìn góńgó tuntun ju ti ìgbàkígbà rí lọ ti 208,223 akéde tí ó ròyìn ní oṣù June. Èyí ti yọrí sí ìpíndọ́gba ìbísí 4.1 nínú ọgọ́rùn-ún ju ìpíndọ́gba iye akéde tọdún tó kọjá tí ó jẹ́ 197,532. Nísinsìnyí, a ní 4,055 ìjọ.