Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn February
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 426 132.5 13.7 61.0 11.1
Aṣá. Déédéé 21,640 59.3 6.7 22.3 5.4
Aṣá. Olù. 7,471 48.9 4.2 14.5 3.5
Akéde 186,541 10.2 0.9 3.5 1.0
ÀRÒPỌ̀ 216,078 Àwọn Tí A Batisí: 160
A dé góńgó tuntun ti 21,640 aṣáájú ọ̀nà déédéé ní oṣù February! Wákàtí tí a dín kù, tí a ń béèrè lọ́wọ́ àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé àti olùrànlọ́wọ́, tí a kéde nínú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti January 1999 ti mú kó ṣeé ṣe fún ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn Jèhófà tí wọ́n ti ṣèyàsímímọ́ láti lo àǹfààní náà láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìsìn aṣáájú ọ̀nà.