Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn July
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 420 136.1 15.1 62.2 11.2
Aṣá. Déédéé 22,937 57.9 7.0 21.8 5.4
Aṣá. Olù. 6,855 48.4 4.7 15.0 3.7
Akéde 193,152 10.2 0.9 3.4 1.0
ÀRÒPỌ̀ 223,364 Àwọn Tí A Batisí: 762
A láyọ̀ láti ròyìn góńgó tó ju ti ìgbàkígbà rí lọ ti 223,364 akéde ní oṣù July. Àròpọ̀ àwọn aṣáájú ọ̀nà tí wọ́n jẹ́ 22,937 jẹ́ góńgó tuntun pẹ̀lú. Apá mìíràn tó tún dùn mọ́ni nínú ìròyìn oṣù July ni góńgó tuntun ti 81,132 ìwé tí a fi sóde. A dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà pé ó ń bù kún iṣẹ́ wa lọ́nà àkànṣe yìí.