Ìroyìn Iṣẹ́ Ìsìn April
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 566 134.2 17.0 61.8 11.6
Aṣá. Déédéé 25,150 55.7 6.2 21.9 5.4
Aṣá. Olù. 22,714 45.8 4.0 14.4 3.3
Akéde 181,583 10.5 1.1 3.6 1.0
ÀRÒPỌ̀ 230,013 Àwọn Tí A Batisí: 701
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti oṣù March béèrè ìbéèrè yìí pé: “Ǹjẹ́ A Lè Mú Kí April 2000 Jẹ́ Oṣù Tí A Tíì Ṣe Dáadáa Jù Lọ?” A láyọ̀ láti ròyìn pé iye àwọn akéde pọ̀ sí i ju ti ìgbàkígbà rí lọ ní oṣù April, wọ́n jẹ́ 230,013. Iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé tún pọ̀ sí i, wọ́n jẹ́ 25,150, nígbà tí àwọn aṣáájú ọ̀nà olùrànlọ́wọ́ pẹ̀lú pọ̀ sí i, wọ́n jẹ́ 22,714. Nítorí ìròyìn àtàtà tí a ní yìí, April 2000 ni “oṣù tí a tíì ṣe dáadáa jù lọ.” A ń fojú sọ́nà fún àwọn ìròyìn iṣẹ́ ìsìn ọjọ́ iwájú.