Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a ó fi lọni ní oṣù December: Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun pẹ̀lú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun. January: Ìwé olójú ewé 192 èyíkéyìí tí ìjọ bá ní, tí a ti tẹ̀ jáde ṣáájú ọdún 1986. February: Ìṣípayá—Òtéńté Rẹ̀ Títóbilọ́lá Kù Sí Dẹ̀dẹ̀!, tàbí ìwé olójú ewé 192 èyíkéyìí tó ti pẹ́ tí ìjọ bá ní. March: Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun. A óò sapá lákànṣe láti bẹ̀rẹ̀ àwọn ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé.
◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tó Wà Báyìí:
Good News for All Nations —Gẹ̀ẹ́sì
◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tuntun Tó Wà:
Watch Tower Publications Index 1999—Gẹ̀ẹ́sì