Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 481 136.3 15.6 63.9 12.0
Aṣá. Déédéé 26,474 54.0 6.3 20.5 5.4
Aṣá. Olù. 5,387 48.8 4.5 15.4 3.9
Akéde 204,443 10.5 1.3 3.7 1.1
ÀRÒPỌ̀ 236,785 Àwọn Tí A Batisí: 563
Inú wa dùn pé àwọn akéde tún pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀, iye wọ́n jẹ́ 236,785. Àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé tún pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ pẹ̀lú, iye wọ́n jẹ́ 26,474. Kí Jèhófà máa bá a nìṣó láti bù kún ìsapá wa bí a ti ń dáhùn sí ìpè náà pé ká máa fi okun ńláǹlà polongo Ìjọba rẹ̀.