Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn February
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 428 130.8 19.0 59.5 12.1
Aṣá. Déédéé 26,863 51.0 7.7 19.2 5.1
Aṣá. Olù. 4,888 45.9 5.7 13.6 3.6
Akéde 203,350 10.1 1.7 3.5 1.1
ÀRÒPỌ̀ 235,529 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 216
Iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé pọ̀ sí i lóṣù yìí o, ju iye ti tẹ́lẹ̀ tó pọ̀ jù lọ! Àwọn 26,863 aṣáájú ọ̀nà déédéé tó ròyìn fi 389 ju iye ti tẹ́lẹ̀, èyí tó jẹ́ 26,474 ní August 2000. Ǹjẹ́ kí Jèhófà máa bá a nìṣó láti bù kún ìsapá wa bí a ti ń dáhùn sí ìpè náà láti túbọ̀ máa pòkìkí Ìjọba rẹ̀.