Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a ó fi lọni ní oṣù September: Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye. (Bí èyí kò bá sí, a lè fi ìwé olójú ewé 192 èyíkéyìí tọ́jọ́ rẹ̀ ti pẹ́ lọni.) October: Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí! Níbi tí wọ́n bá ti fi ìfẹ́ hàn nígbà ìpadàbẹ̀wò, a lè fi ìforúkọsílẹ̀ fún ìwé ìròyìn lọni. November: Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa? tàbí Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun. Bí àwọn èèyàn bá ti ní ìwọ̀nyí tẹ́lẹ̀, a lè fi ìtẹ̀jáde mìíràn tí ọjọ́ rẹ̀ ti pẹ́ lọ̀ wọ́n. December: Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí. A lè fi Iwe Itan Bibeli Mi tàbí Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye lọni bí àfidípò.
◼ A ń rán àwọn alàgbà létí láti ṣiṣẹ́ lórí ìtọ́ni táa là kalẹ̀ nínú Ilé-ìṣọ́nà ti April 15, 1991, ní ojú ìwé 21 sí 23, tó ní í ṣe pẹ̀lú àwọn táa yọ lẹ́gbẹ́ tàbí tí wọ́n yọ ara wọn lẹ́gbẹ́, tí wọ́n lè fẹ́ kí a gbà àwọn padà.
◼ Kì í ṣe Society ló ń kọ ọ̀rọ̀ sínú fọ́ọ̀mù ìbéèrè fún ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ ti akéde kọ̀ọ̀kan. Kí alábòójútó olùṣalága ṣètò fún ìfilọ̀ lóṣooṣù kí a tó fi ìbéèrè fún ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ ti ìjọ lóṣooṣù ránṣẹ́ sí Society, kí olúkúlùkù ẹni tó bá fẹ́ láti gba ìwé tirẹ̀ lè sọ fún arákùnrin tí ń bójú tó ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́. Ẹ jọ̀wọ́, ẹ rántí pé àwọn ìtẹ̀jáde kan wà tó jẹ́ ìbéèrè àkànṣe.
◼ Fídíò Tuntun Tó Wà:
Our Whole Association of Brothers — Gẹ̀ẹ́sì
◼ A ti ṣe àwọn àyípadà tó wà nísàlẹ̀ yìí nínú “Àwọn Ibi Tí A Ó Ti Ṣe Àpéjọpọ̀ Àgbègbè ti Ọdún 2001” tó wà nínú àkìbọnú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti May 2001. Kí alábòójútó olùṣalága ìjọ èyíkéyìí tí a bá ti yí àkókò tàbí ibi tí wọn yóò ti ṣe àpéjọpọ̀ padà jọ̀wọ́ ṣètò kí a ṣèfilọ̀ rẹ̀ ní Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn tí wọn yóò ṣe lẹ́yìn tí wọ́n bá ti rí ìtẹ̀jáde Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa yìí gbà.
October 26-28, 2001
DÁLÙWỌ́N 1 (Yorùbá) Y-1: I sí Z; Y-8: Ìdẹ̀ra, Ilara, Imala, Ìmẹ̀kọ, Ìwòyè, Kájọlà, Masifa, Ọlọ́rundáwa, Olowu, Olupe, Gbàńlà
November 2-4, 2001
DÁLÙWỌ́N 2 (Gẹ̀ẹ́sì) WE-1: A sí J; WE-13: L sí Z
November 9-11, 2001
ÌBÀDÀN 2 (Yorùbá) Y-14 ÀYÀFI Akata, Ìdí Òro, Ìrẹsà Dúdú, Jaṣẹnu, Odò Ọbà, Ọjagbo, àti Onípélé; Y-33.
November 16-18, 2001
UYÓ 4 (Ẹ́fíìkì) EF-4: J sí Z; EF-5: Àwọn ìjọ tí a kò yàn sí Uyó 2
November 23-25, 2001
ÌLỌRIN 2 (Yorùbá) Y-13A; Y-14: Akata, Idi Oro, Ìrẹsà Dúdú, Jaṣẹnu, Odò Ọbà, Ọjagbo, àti Onípélé; Y-18: Ayetẹ́jú Àmùrò, Ẹ̀gbẹ̀, Ìsánlú, Mọ̀pà, àti Odòbùkún
November 30–December 2, 2001
UYÓ 6 (Ẹ́fíìkì) EF-9: Nu sí Z; EF-10: Afaha Ikot Ede, Afaha Offiong; EF-15: N sí Z
December 7-9, 2001
IGWURUTA ALI 8 (Gẹ̀ẹ́sì) EE-4: Unyengala; EE-22: M sí Z; EE-23: J sí Z; EE-28: C sí K
ÙBOGÒ 7 (Ísókó) IS-1; IS-3: A sí I
UYÓ 7 (Ẹ́fíìkì) EF-10: Àwọn ìjọ tí a kò yàn sí Uyó 6 tàbí Uyó 10; EF-15: A sí E
December 14-16, 2001
AGBOR 7 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-10: Oloa, Enede; ME-11: Onyibe, Memeh; ME-17: gbogbo ìjọ ÀYÀFI Afuda, Idumu-Otutu, Ebelle, Ebhoiyi, àti Ujiogba
DÁLÙWỌ́N 8 (Yorùbá) Y-8: Gbogbo ìjọ tí a kò yàn sí Dálùwọ́n 1; Y-9: A sí L
ÙBOGÒ 8 (Ísókó) IS-2; IS-3: J sí Z
January 4-6, 2002
IGWURUTA ALI 10 (Gẹ̀ẹ́sì) EE-2: A sí K; EE-4: O sí Z ÀYÀFI Unyengala; EE-28: L sí M
IKOT EKPENE 8 (Ẹ́fíìkì) EF-11: P sí Z; EF-14: Ikot Obong Edong, Ikot Ubom, Ikot Udo-Ika, Ikot Uko, àti Ikot Umoh Essien
ÙBOGÒ 9 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-7: E sí Z; ME-18: Emu Uno; ME-19: A sí M
January 11-13, 2002
ÙBOGÒ 10 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-6: C sí K; ME-9: B sí O
UYÓ 10 (Ẹ́fíìkì) EF-9: Na sí Nt; EF-10: Etinan, Ikot Abasi Iman, Ikot Ante, Ikot Atang Esen, Ikot Eba, àti Ikot Edibon; EF-15: F sí M
January 18-20, 2002
ÙBOGÒ 11 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà) ME-6: L sí Z; ME-9: P sí Z