Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn September
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 475 134.2 20.3 61.2 12.2
Aṣá. Déédéé 26,882 51.3 9.9 19.9 5.2
Aṣá. Olù. 6,048 47.5 7.4 14.9 3.9
Akéde 213,666 10.5 2.3 3.8 1.1
ÀRÒPỌ̀ 247,071 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 373
A bẹ̀rẹ̀ ọdún iṣẹ́ ìsìn tuntun lọ́nà tó dára. Ní oṣù wa àkọ́kọ́ nínú ọdún iṣẹ́ ìsìn yìí, àwa akéde tún pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ, iye wá jẹ́ 247, 071. Èyí ni ìgbà kẹta tẹ̀ léra tá a tíì pọ̀ jù, bẹ̀rẹ̀ láti oṣù July 2001. A dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà nítorí ìbùkún rẹ̀ lórí àwọn ìgbòkègbodò wa.