Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn April
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St
Aṣá. Àkàn. 459 133.6 30.3 60.2 12.8
Aṣá. Déédéé. 26,999 51.3 13.2 20.2 5.3
Aṣá Olù. 13,487 44.3 10.1 13.8 3.5
Akéde. 207,510 10.1 2.9 3.7 1.1
ÀRÒPỌ̀ 248,455 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 562
A láyọ̀ láti mọ̀ pé ẹ̀ẹ̀kejì rèé nínú ọdún iṣẹ́ ìsìn yìí tí iye àwa akéde tún pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ, iye wa jẹ́ 248,455 ní oṣù April. A ní àwọn akéde 962 láfikún sí iye tá a jẹ́ tẹ́lẹ̀ ní oṣù March. A dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà fún àwọn ìbùkún rẹ̀ lórí àwọn ìgbòkègbodò wa.