Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 504 136.1 38.2 62.5 13.5
Aṣá. Déédéé 27,331 51.0 13.7 20.1 5.4
Aṣá. Olù. 5,533 47.4 11.0 15.8 4.2
Akéde 222,467 10.4 3.3 3.9 1.2
ÀRÒPỌ̀ 255,835 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 463
A láyọ̀ láti parí ọdún iṣẹ́ ìsìn 2002 pẹ̀lú ìbísí nínú iye àwa akéde. Ní oṣù August, iye wa jẹ́ 255,835. Èyí fi 7,380 lé sí iye tá a jẹ́ lóṣù April. A dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà fún ìbùkún rẹ̀ lórí àwọn ìsapá wa.