ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 7/03 ojú ìwé 2-7
  • Àwọn Ìfilọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ìfilọ̀
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2003
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2003
km 7/03 ojú ìwé 2-7

Àwọn Ìfilọ̀

◼ Ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a óò fi lọni ní oṣù July àti August: A lè fi èyíkéyìí nínú àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé 32 wọ̀nyí lọni: Akoso Naa Ti Yoo Mu Paradise Wá, Gbádùn Iwalaaye Lori Ilẹ Ayé Titilae!, Iwọ Ha Nilati Gbàgbọ́ Ninu Mẹtalọkan Bí?, Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Bawo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?, Kí Ní Ń Ṣẹlẹ̀ sí Wa Nígbà Tí A Bá Kú?, Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú?, Orukọ Atọrunwa naa Tí Yoo Wà Titilae, Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi?, Ọ̀nà Tó Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun—Ṣé O Ti Rí I?, àti “Sawo O! Emi Nsọ Ohun Gbogbo Di Ọtun.” September: Ìwé Sún Mọ́ Jèhófà. Bí kò bá sí lọ́wọ́, ẹ lè lo ìwé Kíyè Sí Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì! tàbí Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye, gẹ́gẹ́ bí àfidípò. October: Ilé Ìṣọ́ àti Jí! Níbi tí wọ́n bá ti fìfẹ́ hàn, kí a fi ìwé pẹlẹbẹ Béèrè lọni, kí a sì ṣe àkànṣe ìsapá láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.

◼ Bẹ̀rẹ̀ láti September, ẹṣin ọ̀rọ̀ àsọyé fún gbogbo èèyàn tí àwọn alábòójútó àyíká yóò máa sọ ni, “Kí Nìdí Tí A Fi Ní Láti Máa Bẹ̀rù Ọlọ́run Tòótọ́?”

◼ A ti fi fọ́ọ̀mù Literacy Report méjì-méjì ránṣẹ́ sí ìjọ kọ̀ọ̀kan. Lẹ́yìn tí ẹ bá ti kọ́ ọ̀rọ̀ sí àwọn àlàfo tó wà nínú fọ́ọ̀mù méjèèjì, ẹ fí ẹ̀dà kan ránṣẹ́ sí Society ní August 1. Kí ẹ tọ́jú ẹ̀dà kejì sínú fáìlì ìjọ.

◼ A ti ṣe àwọn ìyípadà tó wà nísàlẹ̀ yìí nínú “Àwọn Ibi Tí A Ó Ti Ṣe Àpéjọ Àgbègbè Ti Ọdún 2003” èyí tó wà nínú àkìbọnú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti May 2003. Kí alábòójútó olùṣalága ìjọ èyíkéyìí tí a bá ti yí déètì tàbí ibi tí wọn yóò ti ṣe àpéjọ padà jọ̀wọ́ ṣètò kí a ṣèfilọ̀ rẹ̀ ní Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn tí wọn yóò ṣe lẹ́yìn tí wọ́n bá ti rí ìtẹ̀jáde Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa yìí gbà.

October 10-12, 2003

MGBOKO UMUORIA 1 (Ìgbò) IB-10, 20

October 24-26, 2003

ÙBOGÒ 2 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-19: K sí Z; ME-22

October 31–November 2, 2003

IKOT EKPENE 1 (Ẹ́fíìkì) EF-11: Ikot Abia Idem, Ikot Abiasom, àti Usaka Annang; EF-12: A sí L; EF-14: Ikot Ubom; EF-18: O sí Z

ÙBOGÒ 3 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-7: E sí Z; ME-18: Emu Uno; ME-19: A sí J

ZARIA 2 (Gẹ̀ẹ́sì) NE-1B: N sí Z; NE-2: A sí J

November 7-9, 2003

ẸNÚGU 1 (Gẹ̀ẹ́sì) EE-12: Ayangba, Ochi-Lagos, Ogugu, Oguma Iso., Okpoga, Otukpa, Ubiadu; EE-17: Amanato, City Layout, Federal Housing, Hilltop, Ihe, Lakecity, Lakeside, Liberty, Odenigbo, àti Trans Ekulu; EE-19: Mainland, Ndiagu, Onuasata, Real Estate, Station (Agbani), Uhueze, Umunevo, Urban, àti Uwani

JOS 3 (Gẹ̀ẹ́sì) NE-3: A sí M; NE-6: Gbogbo ìjọ ÀYÀFI Magami àti Sabongari

ÙLÌ 3 (Ìgbò) IB-5: B sí Z; IB-40

November 14-16, 2003

KATSINA ALA 1 (Gẹ̀ẹ́sì) EE-11A; EE-12: Adoka, Aliade, Etutekpe, Eupi, Igedde Central, Igumale, Obarike Ito, North Bank, South Bank, àti Ugbokolo; EE-26: A sí I; NE-6: Magami àti Sabongari

SULEJA 3 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà) NE-5: A sí F; NE-7: K sí Z; NE-1A: Yelwa-Yauri

November 21-23, 2003

AGBOR 4 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-11: Gbogbo ìjọ àyàfi Memeh àti Onyibe; ME-17: Afuda, Idumu-Otutu, Ebelle, Ebhoiyi, àti Ujiogba

BENIN CITY 4 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-20: A sí I; ME-21: A sí Om

ÙBOGÒ 6 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-6: A sí B; ME-7: A sí D; ME-9: A sí Az; ME-10 ÀYÀFI Enede, Farm Settlement, Igwete, Ishimili, Ndemili, Ogbe Onishe, Oloa, Umuekum, àti Utagba Uno

November 28-30, 2003

AGBOR 5 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-10: Farm Settlement, Igwete, Ishimili, Ndemili, Ogbe Onishe, Umuekum, àti Utagba Uno; ME-14: Àwọn ìjọ tí a kò yàn sí Agbor 3

IKOT EKPENE 5 (Ẹ́fíìkì) EF-11: A sí E àti Ubot Oko; EF-14: J sí Z àti Ikot Obong Edong

December 5-7, 2003

AGBOR 6 (Esan) B-1B

BENIN CITY 6 (Ẹ̀dó) B-1A, 2

IKOT EKPENE 6 (Ẹ́fíìkì) EF-11: J sí O; EF-14: Ibiakpan, Ikot Akpa Edok, Ikot Ekon, Ikot Ikpa, Ikot Udo-Ika, Ikot Uko, àti Ikot Umoh Essien; EF-18: A sí N

MGBOKO UMUORIA 9 (Ìgbò) IB-11, 17; IB-19: A sí M

ÙBOGÒ 8 (Ùròbò) U-2: A sí N; U-3: Ewu, Egbo, Ehere, Iwrogoni, Ogbe, Ohoror, Otovwodo, Uduere, Uduovhori, àti Uneni; U-5; U-6: F sí Z

December 12-14, 2003

IKOT EKPENE 7 (Ẹ́fíìkì) A ti wọ́gi lé e—Jọ̀wọ́ wo Ikot Ekpene 1, Ikot Ekpene 5, àti Ikot Ekpene 6

December 19-21, 2003

AGBOR 8 (Ìgbò) IB-45

January 16-18, 2004

ÙBÓGÒ 12 (Ijaw) RV-1, 2

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́