Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 497 134.0 36.7 63.9 13.6
Aṣá. Déédéé 27,585 52.8 15.6 20.6 5.6
Aṣá. Olù. 5,435 47.4 12.5 16.2 4.3
Akéde 227,279 10.9 3.8 4.1 1.2
ÀRÒPỌ̀ 260,796 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 290
A láyọ̀ láti parí ọdún iṣẹ́ ìsìn 2003 pẹ̀lú ìbísí nínú iye àwa akéde. Ní oṣù August, iye wa jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́tàlá, ọgọ́rùn-ún méje àti mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn-ún [260,796]. A tún ní ìbísí tuntun nínú iye àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé, ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, àti nínú iye àwọn ìwé kékeré àti ìwé pẹlẹbẹ tí a fi sóde. A dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà fún ìbùkún rẹ̀ lórí àwọn ìsapá wa.—Òwe 10:22.