Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn September
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 497 136.0 38.5 62.1 13.6
Aṣá. Déédéé 26,612 52.0 15.0 20.7 5.6
Aṣá. Olù. 5,281 47.8 12.0 16.5 4.4
Akéde 231,321 10.5 3.7 4.0 1.2
ÀRÒPỌ̀ 263,711 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 461
Inú wa dùn pé ìbísí nínú iye akéde la fi bẹ̀rẹ̀ ọdún iṣẹ́ ìsìn 2004. Ní oṣù September, iye wa jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́tàlá ó lé ẹgbẹ̀ẹ́dógún, ọgọ́rùn-ún méje àti mọ́kànlá [263,711]. Iye yìí fi ẹgbẹ̀rún méjì, ọgọ́rùn-ún mẹ́sàn-án àti mẹ́ẹ̀ẹ́dógún [2,915] ju ti oṣù August, tó jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́tàlá, ọgọ́rùn-ún méje àti mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn-ún [260,796], lọ. A gbàdúrà pé kí Jèhófà túbọ̀ máa bù kún ìsapá wa nínú iṣẹ́ ìsìn náà.—1 Kọ́r. 3:6.