Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé tí a ó fi lọni ní December: Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí. Bí kò bá sí, a lè lo Iwe Itan Bibeli Mi tàbí Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye. January: Ìwé Kíyè sí Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì! tàbí ìwé pẹlẹbẹ Ẹmi Awọn Oku—Wọn Ha Le Ran Ọ Lọwọ Tabi Pa Ọ Lara Bi? Wọn Ha Wa Niti Gidi Bi? February: Ìwé Sún Mọ́ Jèhófà la ó fi lọni. Bí kò bá sí, a lè lo ìwé Kíyè sí Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì!, Ìṣípayá—Òtéńté Rẹ̀ Títóbi Lọ́lá Kù Sí Dẹ̀dẹ̀! àti Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye.
◼ Àwọn Ìtẹ̀jáde Tuntun Tó Wà:
Watchtower Library—2003 Edition on CD-ROM [Àkójọ Ìtẹ̀jáde Society Tá A Ṣe Sórí Ike Pẹlẹbẹ Tá À Ń Fi Kọ̀ǹpútà Lò—Ẹ̀dà ti 2003].—Gẹ̀ẹ́sì