Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn August
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 500 127.2 41.3 61.1 13.3
Aṣá. Déédéé 26,723 54.8 16.4 21.2 5.7
Aṣá. Olù. 6,826 48.1 12.4 15.9 4.0
Akéde 236,559 10.8 4.0 4.2 1.2
ÀRÒPỌ̀ 270,608 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 66
Inú wa dùn pé àwọn akéde tí iye wọn jẹ́ 270,608 ló ròyìn lóṣù August, ó sì dára gan-an pé iye tó tíì pọ̀ jù lọ yìí la fi parí ọdún iṣẹ́ ìsìn 2004. Iye yìí fi nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá [10,000] ju iye akéde tá a ní ní August 2003 lọ. Ìtẹ̀síwájú tún wáyé nínú iye àwọn ìwé kékeré àti ìwé pẹlẹbẹ, àti ìwé ìròyìn tá a fi sóde, àti nínú ìpadàbẹ̀wò àti ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. Ìyìn ni fún orúkọ Jèhófà nítorí bó ṣe ń bù kún àwọn ìgbòkègbodò wa.