Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ January 19
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JANUARY 19
Orin 126
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Jẹ́nẹ́sísì 11-16
No. 1: Jẹ́nẹ́sísì 14:1-16
No. 2: Ẹni Tí Ó Dá Ohun Gbogbo (lr-YR orí 3)
No. 3: Báwo Ni Jèhófà Ṣe Ń Mọ Wá? (Aísá. 64:8)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 90
5 min: Àwọn ìfilọ̀ ìjọ. Àwọn ìfilọ̀ tá a mú látinú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa.
10 min: Àwọn Ọ̀rọ̀ Tó Lè Bẹ́gi Dínà Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀pọ̀. Lẹ́yìn ìnasẹ̀ ọ̀rọ̀ ṣókí, lo ìwé Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Awọn Ìjíròrò Bibeli Kí A Sì Máa Báa Nìṣó ojú ìwé 7 sí 12 láti ṣàṣefihàn báwọn ará ṣe lè dáhùn díẹ̀ lára àwọn ọ̀rọ̀ táwọn tó wà ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín máa ń sọ láti fi bẹ́gi dínà ìjùmọ̀sọ̀rọ̀pọ̀.
20 min: “Ṣó O Mọ Èyí Tó Yẹ Kó O Yàn?”a Alàgbà ni kó bójú tó apá yìí. Ka ìpínrọ̀ tó gbẹ̀yìn láti kádìí ìjíròrò náà.
Orin 133
[Àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé]
a Má ṣe jẹ́ kí ìnasẹ̀ ọ̀rọ̀ tó ìṣẹ́jú kan, kó o wá darí àpilẹ̀kọ náà lọ́nà ìbéèrè àti ìdáhùn.